Aare Lyrics By Brymo


Aare Lyrics By Brymo


Eré òkúta àti gíláàsì

Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò

Ọlọ'ọ'pá wá o, ó máa gba rìbá


Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré

Eré òkúta àti gíláàsì


Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò

Ọlọ'ọ'pá wá o, ó máa gba rìbá


Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré

Eré òkúta àti gíláàsì


Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò

Ọlọ'ọ'pá wá o...


Ẹku owurọ o

Ìròyìn láti ìgboro la mú wá kàn yín létí


Wọ'n ní ní òwúrọ' yìí, àwọn ọmọ éèès!

Wọ'n ti jà wọ"gboro

Wọ'n dẹ' ti ń dáná sunlé


Wọ'n ti ń dáná sun oko

Àt'ọkọ' ayọ'kẹ'lẹ' àti èyí tí ò yọ'kẹ'lẹ'

Gbogbo ẹ' ná ń dáná sun


Ẹ gbélé yín o

Ẹ ṣọ'ra yín o

Ẹ pe àwọn ọmọ yín sọ'dọ'


Èyí tí ò bá lọ sílé ìwé, kó jókòó

Kí Ọlọ'run kí ó máa ṣọ' gbogbo wa o

Láyọ' o, ẹ ṣé


Ààrẹ ń bọ' l'ájò

Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin


Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú

Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi

Orí mi ló gbé mi k'ore


Ààrẹ ń bọ' l'ájò

Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin


Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú

Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi

Orí mi ló gbé mi k'ore!

Comments