Adedotun Lyrics By Brymo


Adedotun Lyrics By Brymo 


Awon adan fo loke

Wan foka si oju orun

Wan o ma mo ibi won lo


Eledua lo n shey ike won

Ko keyin si é oré o

O wun o n wa

O wa ni waju re


Adedotun

Oyindamola mi

Ero gbogbo e ba gberin

Adedotun o


Awon adan fo loke

Ni igba igba

Won ku oju orun

Won o ma mo iwun wan n je


Eledua lo n sho wan

Lo n bo wan

Ko pamo si é

Oré ooooooo

O wa lo sokoto

O wa lapo sokoto


Adedotun!

Oyindamola mi

Ero gbogbo e ba gberin

Adedotun o...


Ko pamo si é

Oré o


Owun o n wa

O wa ni waju re

Ore o!

Comments