Akoko Lyrics By Brymo


Akoko Lyrics By Brymo 


Emi ni emi leni na

Okunrin meta at'abo to n forin ko

Emi ni emi lomo na

Okunrin merin at'abo won tenu mo

Mo lanu, mo soro


Mo y'ake, mo fo ro

Omo oloforo, mo j'akara oforo

Emi ni ah, emi ni oh

Emi ma leni to n so nigboro

Emi ni ya, emi ni yo

Awon mama gan soro ni popo


Won le mi l'akoko

Won le mi l'akoko oh

Won le mi l'akoko oh

Won le mi l'akoko oh


Emi ni, okunrin na

T'awon majesi sope o'morin gan

Emi ni, emi lomo na

Gbogbo aradugbo lo n tenu mo

Emi baba olowo


Mo sowo, mo jere

Iwa at'opolo lo n lo

Awon ota ti rupo


Emi ni ah, emi ni oh

Emi ma leni to n so nigboro

Emi ni ya, emi ni yo

Awon omoge redi ni popo


Won le mi l'akoko (iwo l'akoko)

Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko oh)

Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko)

Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko)


Won le mi l'akoko (iwo l'akoko)

Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko oh)

Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko)

Won le mi l'akoko oh (iwo l'akoko)

Comments