Meji Meji Lyrics By Brymo
Meji Meji Lyrics By Brymo
Mò fí iyẹ' mi fo
Mò ri'rè
Mò wò waju, mò w'oké
Ìrè dé
Kí ìjò mọlẹ, mo tún takasúfè
O dún mọ' mí òó
O dún mọ' mí òó
O dún mọ' mí òó òó
O dún mọ' mí òó
Méjì méjì làá d'àiyé ò
Méjì méjì làá d'àiyé ò
Ìfẹ rẹ sí mí, o jìn gángan
Méjì méjì làá d'àiyé ò
Méjì méjì làá d'àiyé ò
Méjì méjì làá d'àiyé ò
Ìfẹ rẹ sí mí, ò jìn gángan
Méjì méjì làá d'àiyé ò
Ọrẹ, dákun rò kò tó lọ
Mò tàràkà, mo ṣubu
Kín tó kọ òun món sọ
Yàrá gbọrọ, lọrá fèsì
Ẹsìn o gbani
Ìwà o lani
Òún tó wùn 'nì ló nwa ní
Ọrẹ, dákun rò kò tó lọ
Mo tàràkà, mo ṣubu
Kín tó kọ òun món sọ
Yàrá gbọrọ, lọrá fèsì
Ẹsìn o gbani
Ìwà o lani
Òún tó wùn'nì ló nwa ni
Mó fi iyẹ mí fo
Mo rí'rè
Mó wò 'wájú mo w'òkè
Ìrè dé
Kí ijó mọlẹ, mo tún takasúfè
O dùn mọ mí óò
O dùn mọ mí óò
O dùn mọ mí óò
O dùn mọ mí óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Ìfẹ rẹ sí mí, o jin gángan
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Ìfẹ rẹ sí mí, o jin gángan
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Ìfẹ rẹ sí mí o jin gángan
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Méjì méjì làá d'àiyé óò
Ìfẹ rẹ sí mí o jin gángan
Méjì méjì làá d'àiyé óọ!
Comments
Post a Comment