Okan Mi Ti Fo Wewe Lyrics By Brymo


Okan Mi Ti Fo Wewe Lyrics By Brymo


Ìyàwó kàn mí npa mi lo, gere

Wọn l'olufoya ni mí oh oh


Ọkùnrin tó lè fẹ mẹta, merin ah ah

Pe mo sà, mo sà, ẹrú dé mí mọlẹ

Ọkàn mi ti fọ' wẹwẹ

Ọkàn mi ti pin yẹ'lẹ'yẹ'lẹ'


Nígbà míràn n'ifẹ fẹ ma wù

Láti ibì ẹwà kóró ẹ'mi mi

Kò tún ní wú


Mo mọ bò ṣe burúkú

O fi lè lẹ tìpẹ'tipẹ'


Má yọ apá mí fún ọ

Òun ló n'ba ẹ' nnú jẹ


Tí 'nu mi ndún

Kò dára

Ọkàn mi ti fò wẹwẹ

Ọkàn mi ti pin yẹ'lẹ'yẹ'


Nígbà míràn, n'ifẹ fẹ má wù

Láti ibì ẹwà kọ'rọ' èmi mi


Kò tún ní wú!

Comments