So Bo’timo Lyrics By Brymo


So Bo’timo Lyrics By Brymo


Ijapa o n'ibi ti o n lo

Kele kele, o n rin, o n lo

Araye n yimu, o n lo

Ero wa, ero lo, o n lo


Ko gba agidi

O ro bi A, B, D


Ti o ba koju mo tie

Ti mo koju mo temi


Bi a ba fi eyin si owo otun

Ki a feyin sowo osi


Ki awa f'eyin rin lati ahin titi de iseyin

Eni ma yini, a yini

Eni o ni yini, ko ni yini


Se bo'timo ore

Se bo'timo ore mi

Se bo'timo mama

Se bo'timo baba mi


Won n tan e

Dakun ye maa tan ara re

T'ire n t'ire


Ye ma ko ara re

Bi o ba sare, bo subu

Iwo lo lara re

B'ole, b'oro

Ore, ma paara ire


Ko gba agidi

O ro bi A, B, D

Ti o ba koju mo tie

Ti mo koju mo temi


Bi a ba fi eyin si owo otun

Ki a feyin sowo osi


Ki awa f'eyin rin lati ahin titi de iseyin

Eni ma yini, a yini

Eni o ni yini, ko ni yini


Se bo'timo ore

Se bo'timo ore mi

Se bo'timo mama

Se bo'timo baba mi ...

Comments