Ejebleje Lyrics By Barry Jhay

Ejebleje Lyrics By Barry Jhay

(Yo D′)

Quality over quantity (o pree)

O ò mọ 'rú ẹ′, ṣọ' ọ ní 'rú ẹ′?

Ejebleje, ẹ′jẹ' ló ń lò, oh no

Ọmọ tó ní ìyá òun ò ní sùn, ohùn gangan ò ní sinmi (and)

As I dey tẹpá mọ′ my hustle, ẹ fún Adekunle mi ní Simi

Ara lamọ', ara lamọ′ (lamọ'), a ò mọ ẹni tó fẹ′ ni dénú (ye)

Ara lamọ', ara lamọ' (lamọ'), a ò mọ ẹni tó fẹ' ni dénú (ye)

Àbí ẹ ò rí aṣinú, ó fi Bíbélì ka kéwú

Ara lamọ', ara lamọ' (lamọ′), a ò mọ ẹni tó fẹ′ ni dénú (ye)

Àbí ẹ ò rí aṣinú, ó fẹ' fi Bíbélì ka kéwú

Confirm ni, no be para oh

Control, no be galala (control, no be galala)

To make money, no be by dragger (no be by dragger)

Oh-oh-oh, aya-ya (oh-oh-oh, aya-ya)

Confirm ni, no be paara oh (no be paara oh)

Control, no be galala (no be galala)

To make money, no be by dragger (fit make money, no be by dragger)

Oh-oh-oh, aya-ya (aya-ya)

Heys

Ọmọ tó bá ta féleféle, ẹ gbá ojú ẹ′ (ẹ gbá ojú ẹ')

Ẹ le pa (ẹ le pa), ó le kwà (ó le kwà), oh-uh-oh

Ọmọ tó bá bẹ′ sí mi, éè ní fara ire lọ, à

Ajurawalọ (ajurawalọ), ti ìjàkadì kọ' (ti ìjàkadì kọ′), ìwọ náà mọ'

Ẹni bínú mi, ò ní ní sinmi

Ẹ'yin enemies, kakulu fuhi

Yes, I mean dede yín, uh

Mo sorry fún gbo-o-o-o-gbo yín oh (gbo-o-o-o-gbo yín oh)

Mo sorry fún gbogbo yín lọ′kọ′ọ'kan (ah-yeah)

Confirm ni, no be para oh

Control, no be galala (control, no be galala)

To make money, no be by dragger (no be by dragger)

Oh-oh-oh, aya-ya (oh-oh-oh, aya-ya)

Confirm ni, no be paara oh (no be paara oh)

Control, no be galala (no be galala)

To make money, no be by dragger (fit make money, no be by dragger)

Oh-oh-oh, aya-ya (aya-ya)

Heys

Ọmọ tó bá ta féleféle, ẹ gbá ojú ẹ′ (ẹ gbá ojú ẹ')

Ẹ le pa (ẹ le pa), ó le kwà (ó le kwà), oh-uh-oh

Ọmọ tó bá bẹ′ sí mi, éè ní fara ire lọ, à

Ajurawalọ (ajurawalọ), ti ìjàkadì kọ' (ti ìjàkadì kọ′), ìwọ náà mọ'......

Comments