2:30 Lyrics By Asake


2:30 Lyrics By Asake


Uhhh

Obah

What demma say?

Obah

Run


Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm


Awa de, awa de de

Awa lọmọ to n sọ ti o seke, ye

Orimọlade gbemi debẹ

Jigan jigan

Ẹsẹ mi o delẹ, delẹ

Alaye mi stop shebẹ

O fẹ jenbi, otun fẹ jenbẹ

Opọ se


Agbawo, fẹnu fo fence

Sun sẹ yin

Amọrawa, sho get?

Abinibi yato s'ability

Ẹsọ fun wọn tan ba teri si

Wọn ma pa lori

Tẹnu kọ, emi promising


Awọn tẹ fọ fun, fọ fun mi

Tori ko sẹ lomi

Many many fẹ dabi mi

Eri bi

Ẹgbọlorun tobi

Mo da aso-ẹbi for my country

You can call me Mr Money


Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm

2:30 fẹlu

Oya ka turn up

Kilẹ to mọ

Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm

Ye, ye, ye

2:30 fẹlu (Thirty fẹlu)

Oya ka turn up

Kilẹ to mọ


Ere moba wa kosi ja

Shokoto pen pe, ye

Ayenika, yebo, yeba

Formation logba, ye ja

Ọmọ'yami ko stay wise

Tranquility, tranquility

I no get time to dey form activity

Kole kalas, I dey find stability


Like abacha, money long infinity

What's the chances?

What's the probability?

To see a better version of me with agility

No you can't fake reality


Ogun, principality and calamity

Mo ti lọ, mo ti pa iyen ti

Bẹbẹ no de for jiji

O shi wa n titi

Still get money like Fifty

Dripping like Fiji

I be real G


Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm

2:30 fẹlu

Oya ka turn up

Kilẹ to mọ

Hmm, hmm, hmm, hmm

Hmm, hmm, hmm, hmm

Ye, ye, ye

2:30 fẹlu

Oya ka turn up

Kilẹ to mọ...

Comments