Great Guy Lyrics By Asake
Great Guy Lyrics By Asake
Ọlọladé mí, Àṣakẹ!
Tune into the king of sound and blues!
I be the vibe you can see in my lifestyle
Ọmọ, mo soft, give them peace sign
Different pattern on my own style
So consistent, no resistance
Leader of the pack, you can call me a brave guy
Steady conquering, I be great guy
Man wey sleep, who go wake am?
This life be like rollercoaster
Ọmọ Ọlọhun, k'ómá s'ere o
Ko wa'lẹ, ibẹ ló ńgbé o
Tí ńba m'ọtí, mo má dé'lé o
J'ayé orí ẹ, wàṣeré o
Ọmọ Ọlọhun, k'ómá s'ere o
Ko wa'lẹ, ibẹ ló ńgbé o
Tí ńba m'ọtí, mo má dé'lé o
J'ayé orí ẹ, wàṣeré o
Satin wọ satin, Paris wọ Berlin
Kà ṣe mí
Orí mí, mà jẹ ńṣẹ̀sín
Ajé mo pé ní, kò jẹ mí
Àrà àdúgbò, ẹ gbà mí
Wọn ní mo tún tí ṣe mí, ṣé bí òun ẹ fẹ ní
I sabi, I no sabi
Party after party, I'm Gucci
Christian Dior, oh my Jesus
I will see you guys soon in the morning o
I gats to go dey with my baby o
Mm-mm, baby, lean on me
Jẹjẹly, jẹjẹly, jẹjẹ o (jẹjẹly)
Rọra gbẹ'nusì, ṣé jẹjẹ o (mm)
Ayé fẹlẹ o, k'ásẹ̀ pẹ'lẹ' o
Ẹ gbé sókè, ẹ má jẹ o wa'lẹ
I be the vibe you can see in my lifestyle
Ọmọ, mo soft, give them peace sign
Different pattern on my own style
So consistent, no resistance
Leader of the pack, you can call me a brave guy
Steady conquering, I be great guy
Man wey sleep, who go wake am?
This life be like rollercoaster
Ọmọ Ọlọhun, k'ómá s'ere o
Ko wa'lẹ, ibẹ ló ńgbé o
Tí ńba m'ọtí, mo má dé'lé o
J'ayé orí ẹ, wàṣeré o
Ọmọ Ọlọhun, k'ómá s'ere o
Ko wa'lẹ, ibẹ ló ńgbé o
Tí ńba m'ọtí, mo má dé'lé o
J'ayé orí ẹ, wàṣeré o
Wáṣeré, o kéré
Ìjà lóde, l'orin d'òwe
Ọmọ ọba, mí o gbé'lé
Saati, mo gbélè, ajà mí lo ń sáaré
Never lose guard, mi o seke
So many things wey my eye don see
Irony, see reality
Normally, I get packaging
Ṣé you go like know, ask Tunde Ednut
CBD, ṣé you see me ri
MTV l'órí AIT
Jesus Christ, wọn fẹ Judas mí
Maybe before you four, five, six
You gats to one, two, three
Two plus two no be one (one, one)
I get the talent, no be cap
My time is prime
Bẹ sí wá kò kpayin, Luku wọ design
Ọmọ ìyámi, jẹ ko shine
Bien malevé
Bien malevé pou toi mo zene fam
Bien malevé pou toi mo zene fam
Tou saki ena so mari lor bateau
Mo trouve signaux signale
Mo trouve signaux signale
Mo trouve signaux signale, pas bateau talaba ki rentre
Comments
Post a Comment