Malaika Lyrics By Teni



Malaika Lyrics By Teni


B'o ti le leju

Wu olorun lo

B'o ti le leju

Wu olorun le

Eli Elijah

Eli Elijah ah ah

Ọrun ṣi ilẹkun


Malaika sọkalẹ wa

Eli Elijah o

Eli Elijah

Eli Elijah ah ah

Ọrun ṣi bo'lẹ

Malaika sọkalẹ wa

Malaika sọkalẹ wa o

Malaika sọkalẹ wa

Malaika sọkalẹ wa o

Malaika sọkalẹ wa


I'm at peace with God and at peace with myself

I surrender, I surrender

No weapon fashioned against me shall prosper

Back to sender, back to sender (back to sender oh, moni back to sender oh)

Lord, I give You my heart and my soul and devotion


You give me peace of mind

And I see all Your works and the good that You are doing

Ṣebi na You change my life


Ogo ni, ogo ni

Ogo ni fun Baba

Ogo ni fun Ọmọ

Ogo ni, ogo ni

Ogo ni fun Ọlọrun ẹmi mimọ

Ogo ni, ogo ni

Ogo ni fun Baba

Ogo ni fun Ọmọ

Ogo ni, ogo ni

Ogo ni fun Ọlọrun ẹmi mimọ


Thank You for all the things that You got me through

Na only me and You

I dey cry night You dey wipe my eyes

Na You dey give me grace o

You say make I get faith o

Make my faith no deflate o

Don't jump from my plate o

People change but You remain the same o


Aimọye eeyan to n ku lojoojumọ

Mi o fi yọ wọn

Mo fi n dupẹ ni

Ẹru n dupẹ ni

Mo fi n dupẹ ni o

Eli Elijah

Eli Elijah ah ah

Ọrun ṣi ilẹkun

Malaika sọkalẹ wa

Eli Elijah o

Eli Elijah

Eli Elijah ah ah

Ọrun ṣi bo'lẹ


Malaika sọkalẹ wa

Malaika sọkalẹ wa o

Malaika sọkalẹ wa

Malaika sọkalẹ wa o

Malaika sọkalẹ wa

Comments