Omoeriwo Lyrics By Dami Dreezy
Omoeriwo Lyrics By Dami Dreezy
Omor
Omo eriwo
Take it or leave it
Esin to wu mi
Ni mo ma se
Ko de si esin to Wu mi oo
Leyin isese
Ifa olokun atun ori eni tio sunwon se
Iwo ni asiwaju wa
Ti ko le je ki awa si se
Eyin omo eriwo
(Yeee)
Eyin omo eriwo
(Ahhh)
Eyin omo eriwo
(lsese agbewa oo e)
Eyin omo eriwo
(Yeee)
Eyin omo eriwo
(Ahhh)
Eyin omo eriwo
(lsese agbewa o0 e)
Ino come to spoil any religion
Or tradition oo
Sugbon laye mi
Mi oni ba won so kotan kotan oo
Oro otito oo
Ni ifa ni ki ama ji so oo
Ate Orin ti mo pa
Ifa jowo wa ba mi so oo
Loke loke lola erin
Loke loke lola efan
Awa ti a gba ifa gbo
Won ma ba wa yo
Eba wa ke de lo
Pe Esin ifa ma Bo
Asiko ti wa to
Ki awa oni isese wa pitan
Eyin omo eriwo
(Yeee)
Eyin onmo eriwo
(Ahhh)
Eyin omo eriwo
(lsese agbewa oo e)
Eyin omo eriwo
(Yeee)
Eyin omo eriwo
(Ahhh)
Eyin omo eriwo
(lsese agbewa ooe)
Awa ti ko ogbon
Won Fe ki a la abo
Oke agba la wa gun oooooo
Won Fe ka jaabo
Sugbon ifa o gba fun won
Ani loju won
Ni ifa ma gba aye lo
Ah ah ah gongon aso ooooo
Eyin omo eriwo
(Yeee)
Eyin omo eriwo
(Ahhh)
Eyin omo eriwo
(Isese agbewa ooe)
Eyin omo eriwo
(Yeee)
Eyin omo eriwo
(Ahhh)
Eyin omo eriwo
(lsese agbewa ooe)
Comments
Post a Comment