Bimida Lyrics By Lil Frosh
Bimida Lyrics By Lil Frosh
Iya ati baba wo n bimida
Emi gan gan motu n tù rá bi
Loruko wu n sé Dara sí
Iya ati baba wo n bimida
Emi gan gan motu n tù rá bi
Loruko wu n sé Dara sí
Gboju wolorun bi karakata ni mo fé
Ki ń ti toju mommy toju daddy ni mo fé
Wo ni pè mo razz wó n pé mi la si bí omo
Wó n mó pé agan mi to tadi mayin bó la tíbi omo
Ò dee n jama jama kó n ma pé ko si future
I start to hustle hard no any artist to fé feature
Worry on my life zino ni pe ki n womisishan
Never stopping la fi awo da Makana is on a mission
No be lie since 2020 fans no Dey see me
Many obstacles but die hard fans still dey feel me
Awon to jeju mi lojosi go still see me win
Blessing me ma loud yoruku lenu bu chimini
Iya ati baba wo n bimida
Emi gan gan motu n tù rá bi
Loruko wu n sé Dara sí
Iya ati baba wo n bimida
Emi gan gan motu n tù rá bi
Loruko wu n sé Dara sí
Wo n ki n sópe ko modé ma dete Tó bá ti lé da igbo gbé
Mó n high Lori no realer Eru iku tolé da igbo gbé
Omo ologo gbogboro tó n para biti mayweather
Shere Nile ma wó nu ojo Shey you see the may weather
Cause eru iku lo ma n jé ko mo
Sha won pelu jekonmo
Aso Gucci sokoto amiri lo n ma je ko wó
Oruju ni je ki ó han
Ojo esin mi mio ni je ko ró
Mo gbélefo to le wole ogba mi o ni decorum
If you know the struggle you go know the pain
Life wasn't easy my brother if you dey the game
Them say money no be fame
Them say Bobby no be tail
I for don peme if no be GOD and cause say OG dey
Iya ati baba wo n bimida
Emi gan gan motu n tù rá bi
Loruko wu n sé Dara sí
Iya ati baba wo n bimida
Emi gan gan motu n tù rá bi
Loruko wu n sé Dara sí
Omo gidi sha lo ye Kaya
Kasitun Jari koshe rere ni tori awon ewe ni ojo iwaju
Boy she rere o boy o shere oooooo
Ba siko bato oluwaye Fuji ma baye tie loo
Ere n Su siwaju ko fi igba kan duro ooo
Eya to bo oko yi daju daju amule lebute ayo o
Emi Loni Fuji mi Tori o Nilu o ni fortune
Igbakan loor igbakan boo
Gbogbo igbakigba wa eledumare je ko ba wa laramu
Isè to sé omo fu ogún odùn
Iyà to jomo fosu mefa bi o ba Kpomo
A Simi leyin omoni
Melo ni ko se o melo ni ko se o
Melo no ko se ile ayé oo
Melo no ko se le ayé ooo
Da da pam da da pam pa pa pam pada
Todo ton to to to to
Melo no ko se le ayé ooo no one but God
Ayinde wasiu mi te ni n teni teni
Ba n da kasa fu omo anifowose o
Eh a ehhhh huuuuuuu
Ba n da kasa fu omo anifowose o
Eh a ehhhh huuuuuuu
Comments
Post a Comment