Kalaa Lyrics By Idowest x Citizen



Kalaa Lyrics By Idowest x Citizen


Kala kan lọ o ję, kala kan lọ o ję, kala

kan lọ ọ je, kala kan lo o je

Kala kan, kala kan, kala kan lọo ję, kala

kan lọ o ję, kala kan lo o ję


-1, -2, ę ni duro wo part 2

1-2 eniduro wo part 2

1-2 eniduro wo part 2

1-2 eniduro wo part 2

Alujannu lo n gbe wa

Beyani atita

Alujannu lo n gbe wa

Beyani atita


E Wonnu won, wonnu wọn, wọnnu won,

Wonnu won, wọnnu wọn, wọnnu won

Aa mọnu won, mọnu wọn, mọnu won,

monu Won, mọnu won, monu won


Opapa parada dagger mi da?

Won fe fun mi Coke ni jo Fantami da?

Tewo si mi aza mi da?

No info no payment wire mi da?

ljauta agba ni now, won fe mumi'lę ni

paki hacker mi da?

Omo lbadan mi o dę mind Bodija, kala

WOju mi bi omọ Bodija

Aljazera, sabatical, apa mo lo'nu store

Zara mi da?

Awon Peter Rufai ę lo wa'bi gba ki Cardi

B to lo di Kadija za


E wonnu won, wọnnu wỌn, wonnu won,

Wonnu won, wonnu won, wonnu won

Aa mọnu won, mọnu wọn, mộnu won,

mọnu NỌn, mọnu won, mọnu wọn

E wonnu wọn, WNỌNNU wọn, wọnnu wọn


Wonnu won, wọnnu wọn, wonnu won

Aa mọnu won, mọnu wọn, mộnu won,

mọnu Won, mọnu won, mọnu won

Kala kan lọ o ję, kala kan lọ o ję, kala

kan lọ ọ ję, kala kan lọ ọ ję

Kala kan, kala kan, kala kan lo o je, kala

kan lọ o ję, kala kan lọ o je

-1, -2, ę ni duro wo part 2


1-2 eniduro wo part 2

1-2 eniduro wo part 2

1-2 eniduro wo part 2


Alujannu lo n gbe wa

Beyani atita

Alujannu lo n gbe wa

Beyani atita


Won ni eni pe ko sowo

Şebi inu igbę lowo wa

Igboro dę loga wa

A wa nibi towo wa

Money money money money

When I pull up is foreign

Brother abeg get that money

To ba lọ broke ko ni funny

Eruku ganja le won sita

Surulere jo wo Shitta

Jaye foreign gbọmọ mẹta

Awa nita....

Comments